Oníwàásù 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Máa yọ̀, ìwọ ọ̀dọ́kùnrin, nígbà tí o ṣì jẹ́ ọ̀dọ́, sì jẹ́ kí ọkàn rẹ máa yọ̀ ní ìgbà ọ̀dọ́ rẹ. Máa ṣe ohun tí ọkàn rẹ bá sọ, sì máa lọ síbi tí ojú rẹ bá darí rẹ sí; ṣùgbọ́n mọ̀ pé Ọlọ́run tòótọ́ máa dá ọ lẹ́jọ́* lórí gbogbo nǹkan wọ̀nyí.+
9 Máa yọ̀, ìwọ ọ̀dọ́kùnrin, nígbà tí o ṣì jẹ́ ọ̀dọ́, sì jẹ́ kí ọkàn rẹ máa yọ̀ ní ìgbà ọ̀dọ́ rẹ. Máa ṣe ohun tí ọkàn rẹ bá sọ, sì máa lọ síbi tí ojú rẹ bá darí rẹ sí; ṣùgbọ́n mọ̀ pé Ọlọ́run tòótọ́ máa dá ọ lẹ́jọ́* lórí gbogbo nǹkan wọ̀nyí.+