Sáàmù 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbogbo èèyàn ló mọ̀ pé àwọn ọlọ́gbọ́n pàápàá ń kú;Àwọn òmùgọ̀ àti àwọn aláìnírònú ń ṣègbé pa pọ̀,+Wọ́n á sì fi ọrọ̀ wọn sílẹ̀ fún àwọn ẹlòmíì.+
10 Gbogbo èèyàn ló mọ̀ pé àwọn ọlọ́gbọ́n pàápàá ń kú;Àwọn òmùgọ̀ àti àwọn aláìnírònú ń ṣègbé pa pọ̀,+Wọ́n á sì fi ọrọ̀ wọn sílẹ̀ fún àwọn ẹlòmíì.+