-
2 Sámúẹ́lì 3:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Nígbà náà, Dáfídì sọ fún Jóábù àti gbogbo àwọn èèyàn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Ẹ fa aṣọ yín ya, ẹ wọ aṣọ ọ̀fọ̀,* kí ẹ sì pohùn réré ẹkún nítorí Ábínérì.” Ọba Dáfídì sì ń rìn bọ̀ lẹ́yìn àga ìgbókùú náà.
-