Oníwàásù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ohun tó ti wà ni yóò máa wà,Ohun tí a sì ti ṣe la ó tún pa dà ṣe;Kò sí ohun tuntun lábẹ́ ọ̀run.*+