Jẹ́nẹ́sísì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+ Jóòbù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jọ̀ọ́, rántí pé amọ̀ lo fi mọ mí,+Àmọ́ ní báyìí, o mú kí n pa dà sínú erùpẹ̀.+
19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+