Òwe 27:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Isà Òkú àti ibi ìparun* kì í ní ìtẹ́lọ́rùn,+Bẹ́ẹ̀ ni ojú èèyàn kì í ní ìtẹ́lọ́rùn. Oníwàásù 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Fàdákà kì í tó ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ fàdákà, bẹ́ẹ̀ ni owó kì í tó ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ọrọ̀.+ Asán ni èyí pẹ̀lú.+
10 Fàdákà kì í tó ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ fàdákà, bẹ́ẹ̀ ni owó kì í tó ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ọrọ̀.+ Asán ni èyí pẹ̀lú.+