Jẹ́nẹ́sísì 30:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà ìkórè àlìkámà,* Rúbẹ́nì+ ń rìn nínú oko, ó sì rí máńdírékì. Ó mú un wá fún Líà ìyá rẹ̀. Réṣẹ́lì wá sọ fún Líà pé: “Jọ̀ọ́, fún mi lára àwọn máńdírékì tí ọmọ rẹ mú wá.”
14 Nígbà ìkórè àlìkámà,* Rúbẹ́nì+ ń rìn nínú oko, ó sì rí máńdírékì. Ó mú un wá fún Líà ìyá rẹ̀. Réṣẹ́lì wá sọ fún Líà pé: “Jọ̀ọ́, fún mi lára àwọn máńdírékì tí ọmọ rẹ mú wá.”