Orin Sólómọ́nì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo mú kí ẹ búra, ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù,Kí ẹ fi àwọn egbin+ àti àwọn abo àgbọ̀nrín inú pápá búra: Pé kí ẹ má ṣe ta ìfẹ́ jí, ẹ má sì ru ìfẹ́ sókè nínú mi, títí á fi wá fúnra rẹ̀.+ Orin Sólómọ́nì 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo mú kí ẹ búra, ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù,Kí ẹ fi àwọn egbin àti àwọn abo àgbọ̀nrín inú pápá búra: Pé kí ẹ má ṣe ta ìfẹ́ jí, ẹ má sì ru ìfẹ́ sókè nínú mi, títí á fi wá fúnra rẹ̀.”+
7 Mo mú kí ẹ búra, ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù,Kí ẹ fi àwọn egbin+ àti àwọn abo àgbọ̀nrín inú pápá búra: Pé kí ẹ má ṣe ta ìfẹ́ jí, ẹ má sì ru ìfẹ́ sókè nínú mi, títí á fi wá fúnra rẹ̀.+
5 Mo mú kí ẹ búra, ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù,Kí ẹ fi àwọn egbin àti àwọn abo àgbọ̀nrín inú pápá búra: Pé kí ẹ má ṣe ta ìfẹ́ jí, ẹ má sì ru ìfẹ́ sókè nínú mi, títí á fi wá fúnra rẹ̀.”+