1 Kọ́ríńtì 13:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìfẹ́ kì í yẹ̀ láé. Àmọ́ tí ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀ bá wà, yóò dópin; tí àwọn ahọ́n àjèjì bá wà,* wọ́n á ṣíwọ́; tí ìmọ̀ bá wà, yóò dópin. 1 Kọ́ríńtì 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Tóò, àwọn mẹ́ta tó ṣì wà nìyí: ìgbàgbọ́, ìrètí àti ìfẹ́; àmọ́ èyí tó tóbi jù lọ nínú wọn ni ìfẹ́.+
8 Ìfẹ́ kì í yẹ̀ láé. Àmọ́ tí ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀ bá wà, yóò dópin; tí àwọn ahọ́n àjèjì bá wà,* wọ́n á ṣíwọ́; tí ìmọ̀ bá wà, yóò dópin.
13 Tóò, àwọn mẹ́ta tó ṣì wà nìyí: ìgbàgbọ́, ìrètí àti ìfẹ́; àmọ́ èyí tó tóbi jù lọ nínú wọn ni ìfẹ́.+