- 
	                        
            
            Àìsáyà 28:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Òdòdó ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ, Èyí tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá, Máa dà bí àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́ ṣáájú ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn. Tí ẹnì kan bá rí i, ṣe ló máa gbé e mì ní gbàrà tó bá ti wà lọ́wọ́ rẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Náhúmù 3:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 Gbogbo ibi olódi rẹ dà bí igi ọ̀pọ̀tọ́ tó ní àkọ́pọ́n èso; Tí a bá mì í jìgìjìgì, àwọn èso náà máa já bọ́ sí ẹnu àwọn ọ̀jẹun. 
 
-