-
Sáàmù 45:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Òjíá àti álóè àti kaṣíà ń já fíkán lára gbogbo aṣọ rẹ;
Ìró àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín látinú ààfin títóbi lọ́lá tí a fi eyín erin ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ ń mú inú rẹ dùn.
-