-
Jeremáyà 18:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ṣé yìnyín lè yọ́ kúrò lára àwọn àpáta tó wà ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Lẹ́bánónì?
Tàbí ṣé omi tútù tó ń ṣàn bọ̀ láti ibi tó jìnnà lè gbẹ?
-