- 
	                        
            
            Orin Sólómọ́nì 4:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        16 Jí, ìwọ atẹ́gùn àríwá; Wọlé wá, ìwọ atẹ́gùn gúúsù. Fẹ́* sórí ọgbà mi. Jẹ́ kí ìtasánsán rẹ̀ gbalẹ̀ kan.” “Jẹ́ kí olólùfẹ́ mi wá sínú ọgbà rẹ̀ Kó sì jẹ àwọn èso rẹ̀ tó dára jù lọ.” 
 
-