Orin Sólómọ́nì 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Oyin inú afárá+ ń kán tótó ní ètè rẹ, ìyàwó mi. Oyin àti wàrà wà lábẹ́ ahọ́n rẹ,+Aṣọ rẹ sì ń ta sánsán bíi ti Lẹ́bánónì.
11 Oyin inú afárá+ ń kán tótó ní ètè rẹ, ìyàwó mi. Oyin àti wàrà wà lábẹ́ ahọ́n rẹ,+Aṣọ rẹ sì ń ta sánsán bíi ti Lẹ́bánónì.