- 
	                        
            
            Orin Sólómọ́nì 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Lójú mi, olólùfẹ́ mi dà bí àpò òjíá+ tó ń ta sánsán, Tó ń sùn mọ́jú láàárín ọmú mi. 
 
- 
                                        
13 Lójú mi, olólùfẹ́ mi dà bí àpò òjíá+ tó ń ta sánsán,
Tó ń sùn mọ́jú láàárín ọmú mi.