-
Orin Sólómọ́nì 2:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “Bí igi ápù láàárín àwọn igi inú igbó,
Ni olólùfẹ́ mi rí láàárín àwọn ọmọkùnrin.
Ó wù mí tọkàntọkàn pé kí n jókòó sábẹ́ ibòji rẹ̀,
Èso rẹ̀ sì ń dùn mọ́ mi lẹ́nu.
-