Orin Sólómọ́nì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìwọ ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́* gan-an, sọ fún mi,Ibi ìjẹko tí o ti ń da àwọn ẹran rẹ,+Ibi tí ò ń mú kí wọ́n dùbúlẹ̀ sí ní ọ̀sán. Ṣé ó wá yẹ kí n dà bí obìnrin tó fi aṣọ bojú*Nínú agbo ẹran àwọn ọ̀rẹ́ rẹ?” Orin Sólómọ́nì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Èmi ni mo ni olólùfẹ́ mi, òun ló sì ni mí.+ Ó ń tọ́jú àwọn àgùntàn+ láàárín àwọn òdòdó lílì.+
7 Ìwọ ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́* gan-an, sọ fún mi,Ibi ìjẹko tí o ti ń da àwọn ẹran rẹ,+Ibi tí ò ń mú kí wọ́n dùbúlẹ̀ sí ní ọ̀sán. Ṣé ó wá yẹ kí n dà bí obìnrin tó fi aṣọ bojú*Nínú agbo ẹran àwọn ọ̀rẹ́ rẹ?”