-
1 Àwọn Ọba 14:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ni ìyàwó Jèróbóámù bá dìde, ó bọ́ sọ́nà, ó sì dé Tírísà. Bí ó ṣe ń dé ibi àbáwọlé, ọmọ náà kú.
-
-
1 Àwọn Ọba 15:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ní ọdún kẹta Ásà ọba Júdà, Bááṣà ọmọ Áhíjà di ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì ní Tírísà, ó sì fi ọdún mẹ́rìnlélógún (24) ṣàkóso.+
-