- 
	                        
            
            Orin Sólómọ́nì 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Ẹ má tẹjú mọ́ mi torí pé mo dúdú, Oòrùn ló sọ mí dà bẹ́ẹ̀. Àwọn ọmọ ìyá mi bínú sí mi; Wọ́n ní kí n máa bójú tó àwọn ọgbà àjàrà, Àmọ́ mi ò bójú tó ọgbà àjàrà tèmi. 
 
-