-
Orin Sólómọ́nì 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ọmú rẹ méjèèjì dà bí ọmọ àgbọ̀nrín méjì,
Ó dà bí ọmọ egbin+ tí wọ́n jẹ́ ìbejì,
Tí wọ́n ń jẹko láàárín àwọn òdòdó lílì.”
-
5 Ọmú rẹ méjèèjì dà bí ọmọ àgbọ̀nrín méjì,
Ó dà bí ọmọ egbin+ tí wọ́n jẹ́ ìbejì,
Tí wọ́n ń jẹko láàárín àwọn òdòdó lílì.”