Orin Sólómọ́nì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Wò ó! O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi. Wò ó! O rẹwà gan-an. Ojú rẹ rí bíi ti àdàbà, lábẹ́ aṣọ tí o fi bojú. Irun rẹ dà bí agbo ewúrẹ́Tí wọ́n ń rọ́ bọ̀ láti orí àwọn òkè Gílíádì.+
4 “Wò ó! O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi. Wò ó! O rẹwà gan-an. Ojú rẹ rí bíi ti àdàbà, lábẹ́ aṣọ tí o fi bojú. Irun rẹ dà bí agbo ewúrẹ́Tí wọ́n ń rọ́ bọ̀ láti orí àwọn òkè Gílíádì.+