Orin Sólómọ́nì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Èmi ni mo ni olólùfẹ́ mi, òun ló sì ni mí.+ Ó ń tọ́jú àwọn àgùntàn+ láàárín àwọn òdòdó lílì.+ Orin Sólómọ́nì 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Olólùfẹ́ mi ló ni mí,Èmi ni mo sì ni olólùfẹ́ mi.+ Ó ń tọ́jú àwọn àgùntàn láàárín àwọn òdòdó lílì.”+
3 Olólùfẹ́ mi ló ni mí,Èmi ni mo sì ni olólùfẹ́ mi.+ Ó ń tọ́jú àwọn àgùntàn láàárín àwọn òdòdó lílì.”+