Orin Sólómọ́nì 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lójú mi, olólùfẹ́ mi rí bí ìdì ewé làálì,+Láàárín àwọn ọgbà àjàrà Ẹ́ń-gédì.”+