Ẹ́kísódù 38:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.
8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.