Sáàmù 89:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Apá rẹ lágbára;+Ọwọ́ rẹ lókun,+Ọwọ́ ọ̀tún rẹ sì ga sókè.+