Míkà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ mú orí yín pá, kí ẹ sì fá irun yín torí àwọn ọmọ yín ọ̀wọ́n. Ẹ mú orí yín pá bíi ti ẹyẹ idì,Torí wọ́n ti kó wọn kúrò lọ́dọ̀ yín lọ sí ìgbèkùn.”+
16 Ẹ mú orí yín pá, kí ẹ sì fá irun yín torí àwọn ọmọ yín ọ̀wọ́n. Ẹ mú orí yín pá bíi ti ẹyẹ idì,Torí wọ́n ti kó wọn kúrò lọ́dọ̀ yín lọ sí ìgbèkùn.”+