ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 139:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Kí n tó sọ̀rọ̀ jáde lẹ́nu,

      Wò ó, Jèhófà, o ti mọ gbogbo ohun tí mo fẹ́ sọ.+

  • Sáàmù 139:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Irú ìmọ̀ bẹ́ẹ̀ kọjá òye mi.*

      Ó kọjá ohun tí ọwọ́ mi lè tẹ̀.*+

  • Sáàmù 147:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Olúwa wa tóbi, agbára rẹ̀ sì pọ̀;+

      Òye rẹ̀ ò ṣeé díwọ̀n.+

  • Àìsáyà 55:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 “Torí bí ọ̀run ṣe ga ju ayé lọ,

      Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín,

      Èrò mi sì ga ju èrò yín.+

  • Róòmù 11:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ọrọ̀ àti ọgbọ́n àti ìmọ̀ Ọlọ́run mà jinlẹ̀ o! Ẹ wo bí àwọn ìdájọ́ rẹ̀ ṣe jẹ́ àwámáridìí tó, tí àwọn ọ̀nà rẹ̀ sì kọjá àwárí!

  • 1 Kọ́ríńtì 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Nítorí “ta ló ti wá mọ èrò inú Jèhófà,* kí ó lè kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́?”+ Àmọ́ àwa ní èrò inú Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́