Àìsáyà 30:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Odò àti ipadò máa wà lórí gbogbo òkè ńlá tó rí gogoro àti gbogbo òkè kéékèèké tó ga,+ ní ọjọ́ tí a pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ tí àwọn ilé gogoro bá ṣubú.
25 Odò àti ipadò máa wà lórí gbogbo òkè ńlá tó rí gogoro àti gbogbo òkè kéékèèké tó ga,+ ní ọjọ́ tí a pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ tí àwọn ilé gogoro bá ṣubú.