-
Míkà 7:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ọ̀tá mi pẹ̀lú yóò rí i,
Ojú yóò sì ti ẹni tó ń sọ fún mi pé:
“Jèhófà Ọlọ́run rẹ dà?”+
Ojú mi yóò rí i.
Wọn yóò tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ bí ẹrẹ̀ lójú ọ̀nà.
-