7 Ohun tí Jèhófà, Olùtúnrà Ísírẹ́lì, Ẹni Mímọ́+ rẹ̀ sọ nìyí, fún ẹni tí wọ́n kórìíra,+ ẹni tí orílẹ̀-èdè náà kórìíra, fún ìránṣẹ́ àwọn alákòóso:
“Àwọn ọba máa rí i, wọ́n sì máa dìde,
Àwọn ìjòyè máa tẹrí ba,
Nítorí Jèhófà, ẹni tó jẹ́ olóòótọ́,+
Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì, ẹni tó yàn ọ́.”+