Àìsáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí. Àìsáyà 49:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+
7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.
8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+