Àìsáyà 49:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+
8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+