Sáàmù 96:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 96 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà.+ Ẹ kọrin sí Jèhófà, gbogbo ayé!+ Sáàmù 98:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+ Ìfihàn 14:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n sì ń kọ orin kan tó dà bí orin tuntun+ níwájú ìtẹ́ àti níwájú àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ àti àwọn àgbààgbà náà,+ kò sì sí ẹnì kankan tó lè mọ orin náà àfi àwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì+ (144,000) tí a ti rà látinú ayé.
98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+
3 Wọ́n sì ń kọ orin kan tó dà bí orin tuntun+ níwájú ìtẹ́ àti níwájú àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ àti àwọn àgbààgbà náà,+ kò sì sí ẹnì kankan tó lè mọ orin náà àfi àwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì+ (144,000) tí a ti rà látinú ayé.