Ẹ́kísódù 32:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àmọ́, tí o bá fẹ́, dárí jì wọ́n;+ bí bẹ́ẹ̀ kọ́, jọ̀ọ́, pa mí rẹ́ kúrò nínú ìwé rẹ tí o kọ.”+ 33 Àmọ́ Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Màá pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣẹ̀ mí rẹ́ kúrò nínú ìwé mi.
32 Àmọ́, tí o bá fẹ́, dárí jì wọ́n;+ bí bẹ́ẹ̀ kọ́, jọ̀ọ́, pa mí rẹ́ kúrò nínú ìwé rẹ tí o kọ.”+ 33 Àmọ́ Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Màá pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣẹ̀ mí rẹ́ kúrò nínú ìwé mi.