Jeremáyà 33:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní àkókò yẹn, a ó gba Júdà là,+ Jerúsálẹ́mù á sì máa wà ní ààbò.+ Ohun tí a ó sì máa pè é ni: Jèhófà Ni Òdodo Wa.’”+
16 Ní àkókò yẹn, a ó gba Júdà là,+ Jerúsálẹ́mù á sì máa wà ní ààbò.+ Ohun tí a ó sì máa pè é ni: Jèhófà Ni Òdodo Wa.’”+