Sáàmù 121:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ń ṣọ́ ọ. Jèhófà ni ibòji+ tó wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.+