-
Àìsáyà 45:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí ìránṣẹ́ mi Jékọ́bù àti Ísírẹ́lì àyànfẹ́ mi,
Màá fi orúkọ rẹ pè ọ́.
Màá fún ọ ní orúkọ tó lọ́lá, bó ò tiẹ̀ mọ̀ mí.