Àìsáyà 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Fetí sílẹ̀! Ọ̀pọ̀ èèyàn wà lórí òkè;Ìró wọn dà bí ìró ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn! Fetí sílẹ̀! Ariwo àwọn ìjọba,Ti àwọn orílẹ̀-èdè tó kóra jọ!+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ń pe àwọn ọmọ ogun jọ.+
4 Fetí sílẹ̀! Ọ̀pọ̀ èèyàn wà lórí òkè;Ìró wọn dà bí ìró ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn! Fetí sílẹ̀! Ariwo àwọn ìjọba,Ti àwọn orílẹ̀-èdè tó kóra jọ!+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ń pe àwọn ọmọ ogun jọ.+