-
Ẹ́kísódù 10:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Na ọwọ́ rẹ sí ọ̀run, kí òkùnkùn lè bo ilẹ̀ Íjíbítì, òkùnkùn tó máa ṣú biribiri débi pé á fẹ́rẹ̀ẹ́ ṣeé fọwọ́ bà.”
-
-
Sáàmù 104:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 O mú kí òkùnkùn ṣú, alẹ́ sì lẹ́,+
Gbogbo ẹranko inú igbó sì ń jẹ̀ kiri.
-