Àìsáyà 26:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà, o máa fún wa ní àlàáfíà,+Torí pé gbogbo ohun tí a ṣe,Ìwọ lo bá wa ṣe é.