Sáàmù 111:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ jẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́ òdodo;+נ [Núnì] Gbogbo àṣẹ rẹ̀ ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé.+ ס [Sámékì] 8 Wọ́n ṣeé gbára lé ní gbogbo ìgbà, ní báyìí àti títí láé;ע [Áyìn] Inú òtítọ́ àti òdodo ni wọ́n ti wá.+ Sáàmù 119:137 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 137 Olódodo ni ọ́, Jèhófà,+Àwọn ìdájọ́ rẹ sì tọ́.+
7 Àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ jẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́ òdodo;+נ [Núnì] Gbogbo àṣẹ rẹ̀ ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé.+ ס [Sámékì] 8 Wọ́n ṣeé gbára lé ní gbogbo ìgbà, ní báyìí àti títí láé;ע [Áyìn] Inú òtítọ́ àti òdodo ni wọ́n ti wá.+