- 
	                        
            
            Àìsáyà 43:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì, Olùgbàlà rẹ. Mo ti fi Íjíbítì ṣe ìràpadà fún ọ, Mo sì ti fi Etiópíà àti Sébà dípò rẹ. 
 
-