Àìsáyà 45:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ kóra jọ, kí ẹ sì wá. Ẹ jọ sún mọ́ tòsí, ẹ̀yin tí ẹ yè bọ́ látinú àwọn orílẹ̀-èdè.+ Wọn ò mọ nǹkan kan, àwọn tó ń gbé ère gbígbẹ́ kiri,Tí wọ́n sì ń gbàdúrà sí ọlọ́run tí kò lè gbà wọ́n.+
20 Ẹ kóra jọ, kí ẹ sì wá. Ẹ jọ sún mọ́ tòsí, ẹ̀yin tí ẹ yè bọ́ látinú àwọn orílẹ̀-èdè.+ Wọn ò mọ nǹkan kan, àwọn tó ń gbé ère gbígbẹ́ kiri,Tí wọ́n sì ń gbàdúrà sí ọlọ́run tí kò lè gbà wọ́n.+