Diutarónómì 33:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+
26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+