Ìfihàn 18:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbogbo orílẹ̀-èdè ti kó sọ́wọ́ rẹ̀ torí wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀,+ àwọn ọba ayé sì bá a ṣe ìṣekúṣe,+ àwọn oníṣòwò* ayé sì di ọlọ́rọ̀ torí ó ń gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ lọ́nà tó bùáyà, kò sì nítìjú.”
3 Gbogbo orílẹ̀-èdè ti kó sọ́wọ́ rẹ̀ torí wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀,+ àwọn ọba ayé sì bá a ṣe ìṣekúṣe,+ àwọn oníṣòwò* ayé sì di ọlọ́rọ̀ torí ó ń gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ lọ́nà tó bùáyà, kò sì nítìjú.”