Ìfihàn 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bó ṣe ṣe ara rẹ̀ lógo tó àti bó ṣe gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú tó, bẹ́ẹ̀ náà ni kí ẹ jẹ́ kó joró, kó sì ṣọ̀fọ̀ tó. Torí ó ń sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: ‘Mo jókòó bí ọbabìnrin, èmi kì í ṣe opó, mi ò sì ní ṣọ̀fọ̀ láé.’+
7 Bó ṣe ṣe ara rẹ̀ lógo tó àti bó ṣe gbé ìgbé ayé gbẹdẹmukẹ láìnítìjú tó, bẹ́ẹ̀ náà ni kí ẹ jẹ́ kó joró, kó sì ṣọ̀fọ̀ tó. Torí ó ń sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: ‘Mo jókòó bí ọbabìnrin, èmi kì í ṣe opó, mi ò sì ní ṣọ̀fọ̀ láé.’+