Dáníẹ́lì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọba wá pàṣẹ pé kí wọ́n pe àwọn àlùfáà onídán, àwọn pidánpidán, àwọn oṣó àti àwọn ará Kálídíà* láti rọ́ àwọn àlá ọba fún un. Torí náà, wọ́n wọlé, wọ́n sì dúró níwájú ọba.+
2 Ọba wá pàṣẹ pé kí wọ́n pe àwọn àlùfáà onídán, àwọn pidánpidán, àwọn oṣó àti àwọn ará Kálídíà* láti rọ́ àwọn àlá ọba fún un. Torí náà, wọ́n wọlé, wọ́n sì dúró níwájú ọba.+