-
Diutarónómì 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+
-
-
Jóẹ́lì 1:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwọn èso* ti bà jẹ́ kí wọ́n tó fi ṣọ́bìrì kó o.
Àwọn ilé ìkẹ́rùsí ti di ahoro.
Wọ́n ti ya àwọn ibi tí wọ́n ń tọ́jú ọkà sí lulẹ̀, torí ọkà ti gbẹ dà nù.
-