Lúùkù 21:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “Àmọ́ ẹ kíyè sí ara yín, kí àjẹjù, ọtí àmujù + àti àníyàn ìgbésí ayé má bàa di ẹrù pa ọkàn yín,+ láìròtẹ́lẹ̀ kí ọjọ́ yẹn sì dé bá yín lójijì Róòmù 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+
34 “Àmọ́ ẹ kíyè sí ara yín, kí àjẹjù, ọtí àmujù + àti àníyàn ìgbésí ayé má bàa di ẹrù pa ọkàn yín,+ láìròtẹ́lẹ̀ kí ọjọ́ yẹn sì dé bá yín lójijì
13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+