Àìsáyà 40:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ẹnì kan wà tó ń gbé orí òbìrìkìtì* ayé,+Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi tata,Ó ń na ọ̀run bí aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó ní ihò wínníwínní,Ó sì tẹ́ ẹ bí àgọ́ láti máa gbé.+ Àìsáyà 42:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+
22 Ẹnì kan wà tó ń gbé orí òbìrìkìtì* ayé,+Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi tata,Ó ń na ọ̀run bí aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó ní ihò wínníwínní,Ó sì tẹ́ ẹ bí àgọ́ láti máa gbé.+
5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+